O tíì jẹ àfikún sinú igba ọjà
Àwọn Ètò Àtìlẹyìn ọjà UCare
Basic Plan
IpilẹṣẹÈTÒ
Plus Plan
Ni afikunÈTÒ
Platinum Plan
PlatinumÈTÒ

Ẹ̀tọ́ ọjà tí a ti sún síwájú tí ó tó ọdún 3

Available
Available
Available

Atunṣe ọfẹ labẹ atilẹyin ọja ti o gbooro sii

Available
Available
Available

Ààbò ẹ̀tọ́ ọjà ilẹ̀ òkèrè (Ọdún 1)

Not Available
Available
Available

Ètọ́ ọjà tó ṣè ṣì bàjẹ́

Not Available
Available
Available

25% oye àtúnṣe (ìṣẹ̀lẹ̀ kọ̀ọ̀kan) lábẹ́ ẹ̀tọ́ ọjà tó ṣè sì bàjẹ́. Ó ní ṣe pẹ̀lú T àti C*

Not Available
Available
Available

idasonu bibajẹ

Not Available
Not Available
Available

Idaabobo ina

Not Available
Not Available
Available
àwọn ìlànà àtẹ̀lé àti àwọn òfin
Atilẹyin ọja labẹ UBUY ko ni bo nkan wọnyi:

Wọ́n tún ẹ̀rọ náà ṣe ní ibùdó iṣẹ́ tí a kò fọwọ́sí àyàfi tí UBUY bá fọwọ́si.

Ìbàjẹ náà wáyé látí fífọ́ tí a dìídì ṣe.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbàjẹ́ tí a fura sí ẹ̀gbẹ́ ọjà kan náà tàbí ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.

Kíká kò tàbí àwọn àbàwọ́n ní ara ẹ̀rọ tàbí èyíkèyí ìbàjẹ́ ìkunra mìíràn.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ tàbí àpapọ̀ ìbàjẹ́ gẹ́gẹ́ bíi fífọ́̀ àti ìtànkálẹ̀ omi ní àsìkò kan náà àti ìpín kíkún nínú omi.

Àwọn ìkùnà tí ó jẹ́ àbájáde lílo ní ìlòkulò, àìṣedéédé tí a mọ̀ọ́mọ ṣè, àwọn ètò tí kò tọ́, ìpín tí kò tọ́ àti lílo àwọn ohun èlò tí kò yẹ.

Wọ́n yí àwọn nọḿbà ìtẹ̀léra padà, wọ́n tọwọ́ bọ́ tàbí yọ kúrò díẹ̀ tàbí pátápátá, tàbí kí wọ́n yọ àmì náà kúrò.

Àwọn èròjà tí ó tẹ̀lẹ́ ọjà.

Ìtọ́jú déédéé àti ìmọ́tótó.

Ìbàjẹ̀ ti data/ẹ̀rọ/sọ́fútiwià nítorí àkóràn kòkòrò àti irú rẹ̀.

Kíkùnà láti dáàbòbò àwọn ẹ̀rọ rẹ lọ́wọ́ àwọn kòkòrò ajẹnirun àti àwọn eku abbl.

Àwọn ẹ̀yà tí ó ṣe é lò gẹ́gẹ́ bí aṣẹ̀ nínú ẹ̀rọ ìwẹ̀nùmọ́ omi tàbí ẹ̀rọ ìgbóná ilé ìdáná, èyí tí wọ́n ṣe láti pẹ́ fún ìgbésí ayé kan nítorí náà oníbàárà rọ́pò rẹ̀ kò ní ààbò.

Ìfiránṣẹ́ àtí oníbodè tí a bá fi ìpààrọ̀ ránṣẹ́ sí ọ.

Èyíkèyí ìbàjẹ́ tí ó bá ṣẹlẹ̀ nípa àtúnṣe irú tí ẹni tó ṣé kò fọwọ sí pẹ̀lú ìkùnnà láti tẹ̀lé àwọn ìlànà àwọn tó ṣe é.

Ẹtọ́ ọjà kò ṣe é gbé ká

Ẹ̀tọ́ ọjà kò ní bo ìgbàpadà àlàyé èyíkèyí ọjà tó ní ọ̀nà láti fi data pamọ́ sínú afẹ́fẹ lórí ẹ̀rọ.́

UBUY lè fagilé ẹ̀tọ́ ọjà fún ohun kan àti dá iye-owó ẹ̀tọ̀ ọjà padà tí wọn bá rò pé ohun náà kò yẹ fún ẹ̀tọ̀ ọjà.

Terms and Condition
Bi o ṣe le beere atilẹyin ọja
Láti gba àtìlẹyìn ọjà, lọ sí àwọn ọjà tí o béèrè fún nínú àkántì rẹ kí o sì tẹ “claim warranty❠fún irufẹ́ ọjà. Yan àwọn Ọdún
1

Ní ìṣẹ̀lẹ̀ àbàwọ́n tàbí ìbàjẹ́ ọjà, oníbáárà gbọ́dọ̀ mú ọjà ló sí ibùdó iṣẹ́ tí a ti ṣé tàbí ilé iṣẹ́ tí a fún ní àṣẹ pẹ̀lú ìwé-ọjà gangan tí a fi ra ọjà náà. Tó bá jẹ́ pé ibùdó iṣẹ́ bá béèrè fún owó àtúnṣe nígbànáà oníbàárà gbọ́dọ̀ fi ìwé ọjà kan náà ránṣẹ́ sí UBUY fún ìdápadà nípa bíbéèrè fún ẹ̀tọ́ ọjà nípasẹ̀ àkántì rẹ̀

2

Tó bá jẹ́ pé arí ibi àwọn ẹ̀yà tó ti bàjẹ́, kí oníbáárà kàn sí UBUY, Tí àwọn ẹ̀yà bá má a wà nígbànáà ni UBUY yóó firánṣẹ́ sí oníbáárà àti oníbáárà yóó ní láti sanwó fún ìfiránṣẹ́ àti oníbodè. Ti kò bá sí nígbànáà oníbáárà lè ra ọjà náà ní ọ̀dọ̀ rẹ̀ UBUY yíò dá ara iye-owó ọjà padà (ìfiránṣẹ àtí tí oníbodè ni a kò ní dápadà)

3

Tó bá jẹ́ pé ọjà kò ṣiṣẹ́ rárá tí kò sì ṣeé tún ṣe nígbànáà ni UBUY yóó wá ìrọ̀pò fún oníbáárà (lẹ́yìn tí wọ́n ti fi Ìdíyelé kun*), àwọn oníbárà yíò ní láti san owó ìfiránṣẹ́ àtí tí oníbodè. Tí kò bá sí ìrọ́pò nígbànáà UBUY yóò dá iye-owó ọjà padà (lẹ́yìn tí wọ́n ti fi Ìdíyelé kun*)

4

Ní ìṣẹ̀lẹ̀ láti gbà a fún iná, o gbọdọ̀ pèsè àwọn ìwé wọ̀nyí sí ilé-iṣẹ́ tí a fún ní àṣẹ tàbí UBUY:

  • Ẹ̀rọ náà ní láti wà níbẹ̀ kí wọ́n sì fifún UBUY ní ipò èyíkéyìí.
  • Ìṣẹ̀lẹ̀ iná òjijì níkán ní ààbò ìsanpadà wà fún.
  • Ẹ̀dà ìwé-ọjà tí a fi ra ọjà ní orúkọ oníbáárà. Ẹ̀dà káàdì ìdánimọ̀ oníbáárà.
  • Ẹ̀dà ìjábọ̀ ẹ̀ka iná tí wọ́n buwọ́lù tí wọ́n sì fi òòlù lù dáadáa.
5

Ìdíyelé yóó wà èyí tí ó dá lórí ọdọọdún tí yóó sí wà bí ìwọ̀nyí

  • Ọdún 1 - 10% ti iye ọjà
  • Ọdún 2 - 20% ti iye ọjà
  • Ọdún 3 - 30% ti iye ọjà